Omo’ba Lyrics b y Pelumi Deborah Feat. George Alao

Share this post:

Pelumi Deborah and George Alao Lyrics

Read the lyrics below and sing along to Omo’ba captivating melodies by Pelumi Deborah, featuring George Alao.

Cover art for Omo Oba by Pelumi Deborah featuring George Alao
Omo’ba Cover Art

Pelumi Deborah & George Alao – Omo’ba Lyrics

Seb’ emi na re o, omo Oba
Alemi na re o, omo Oba
Alemi na re o, omo Oba
Why look any further
Seb’ emi na re o, omo Oba

Eni Oba nke
Eni Oba nge
Eni Oba n wo
Eni Oba ntoju
Oba lo to mi dagba
Oba lo womi dagba
Oba lo ran mi ni şe
Oba lo f’ ami simi Lara
Oba lo da ororo lemi lori
O f’ade iyin de mi lori
O f’ ade ogo demi lori
O f’ ade ewa demi lori

Ohun lo ni ki n duro deede
Olohun wa lehin mi bi akoni eleru
O ni awon omo kiniun
Won a ma se alaini
Ebi a si maa pawon
Sugbon awon to duro de Oluwa
won ko ni s’ alaini ohun to dara
Emi ti gbe Oluwa ka iwaju mi nigbagbogbo
Nitori O wa lehin mi eh
Aki yio si mi nipo

Won o le si mi nipo eh
Mo ni won o le si mi nipo
Emi o see si nipo
Tori Oba lo ran mi nise, eh!
Oba lo ran mi nise

Baa ranni nise Oba aa fi toba je
Baa ranni nise Oba aa fi toba je
Oba lo ran mi nise
Ohun lo ni ki n ma beru
Ohun loni ki n ma foya
Ohun lo ni ki n te siwaju

Seb’ emi naa re oo, omo Oba
A lemi naa re o om’ Oba
I can’t help it
Seb’ emi naa re oo eeehhhh
Seb’ emi naa re o om’ Oba o eh
Seb’ emi naa re omo
Seb’ emi naa re oo

Ajike
Ajige
Apeke
Asake
Ayanfe

Ololufe mi lo pemi
O ni kin duro deede
O ni kin mase beru
O ni kin mase foya
Seb’ emi na re
Omo’ ba
Seb’ emi na re
Omo’ ba
Seb’ emi na re
Omo’ ba
Seb’ emi na re
Omo’ ba

Omo’ba ni e mase beru
Omo’ba ni e mase foya

Seb’ emi naa re oo, omo Oba
A lemi naa re o om’ Oba
I like this song

Oba nke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re omo’ ba
Oba nke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re omo’ ba
Oba nkę mi
Oba n wo mi dagba
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re omo’ ba
One more time
Oba nke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re omo’ ba
Oba nke mi
Oba n lo ni kin ma beeru
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re omo’ ba
Oba nke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re omo’ ba

Tori onawo ife si mi
Tori onawo iye si mi
Tori onawo ayo si mi…

Want to keep up with trending songs? Check out more song lyrics here and follow us on and Facebook

TAGS



Source link